text
stringlengths 35
117
| audio
audioduration (s) 3.22
16.5
| speaker_id
stringclasses 1
value | age_group
stringclasses 1
value | domain
stringclasses 1
value | gender
stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
wùnmi ìyàwó mohbad tú àṣírí bí ọkọ rẹ ṣe kú ganan nílẹẹjọ
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
abirú kí lélẹyìí ọkọ ojú omi tó ń gbé ọgọrùnún èrò ló dojú dé láàrin agbami
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
èyí [um] lohun tí ṣádì ọṣùpá sọ lásìkò ìkẹkọọgboyè rẹ ní [um] fásitì ìbàdàn
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
òde àdúgbò yìí ti wọ gàá ẹwọn gbére ládàjọ ṣó o sì
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ó déèwọ ẹnikẹni [um] ò gbọdọ lo ike takewé [um] lẹkọọ mọ ìjọba
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
àáfàá [um] àgbà ilé ìbàdàn shoji abdulfatai gegeji alaga [um] jáde láyé
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ẹgbẹ òṣìṣẹ làwọn kò làwọn kò fara mọ àfikún owó oṣù tuntun tìjọba kéde
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
nítorí àwọn ọrẹ ọmọ ẹ tí wọn láwọn fẹẹ sìnkú ẹ baba mohbad fàbínú yọ
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
èèyàn mẹẹẹdọgbọn jóná kú lásìkò tí mọtò akérò [um] méjì forí sọra wọn [um]
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ìbejì ọràn táyé àti kèhìndé lóò fọ ṣọọbù [?] ladọèkìtì ni wọn bá mú wọn
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
iléeṣẹ ọlọpàá ìpínlẹ èkó bẹrẹ ìwádìí nípa agbófinró tó gun aráàlú pa
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
orí kó òṣìṣẹ inec yọ lọwọ àwọn ajínigbé
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ọlọpàá fòfin de yìnyín bágà lákòókò [um] ọdún kérésì nípínlẹ ogun
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
wọn ti mú tíṣà tó fipá bá akẹkọọ rẹ lò pọ ńìlọrin
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
[um] ayé tí wàá bàjẹ o wọn bá ọkàn èèyàn méjì lọwọ wáṣíù àtàwọn [um] ọrẹ ẹ
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
àṣírí [?] tú àjùlọ ní ayédèrú ìbuwọlù akérèdọlù làwọn ọmọlẹyìn rẹ fi ń ṣe oríṣìíríṣìí nǹkan
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
èyí lẹ ọ àwọn agbégbọn pààyàn wọn tún jí àwọn mẹẹẹdọgbọn gbé lọ
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ìjà rẹpẹtẹ láàrin ẹgbẹ onímọtò àwọn ọmọ ọṣọdì làwọn ò fẹ mc olomini nípò mọ
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ẹ wojú àwọn géńdé méjì yìí ìbọn ni wọn ń rọ tà fáwọn ajínigbé
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
azeez pariwo ni mi ò fẹẹ kú báyìí adájọ ẹ tu èmi àti rọkẹbètè
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
[um] owó ọlọpàá tẹ ṣẹgun ògbólógbòó adigunjalè [um] tó ń yọ wọn lẹnu ní kwara
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ọdọọdún ní tinubu ní ká máa gbààyàn ṣíṣe ọlọpàá báyìíègbétókùn
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
lórí bó ṣe fẹẹ ṣa ìyàwó rẹ pa lòkìtìpápá adájọ ju kalejayé sẹwọn ọdún márùndínláàádọta
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
iléeṣẹ táwọn ọmọkùnrin yìí ń bá ṣiṣẹ ni wọn jà lọlẹ
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ṣẹyìn náà ti gbọ ohun tó ṣẹlẹ sí lálàá onítìátà
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ọlàdìmejì ń rìn ní bèbè ẹwọn ìbọn àgbélẹrọ àti ọpọ ọtá ni wọn kà mọ ọn lọwọ
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ọlọrun gbà wá o ayédèrú ọtí [um] lóríṣìíríṣìí lọkùnrin yìí ń pọn ta fáráàlú ní badág [um]
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
òpùrọ lọkọ mi o ò ti bímọ mẹrin síta kó tóó fẹ mi mi ò ṣe mọ
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
owó ti bá méjì lára àwọn ajínigbé tó lọọ jí àwọn òṣìṣẹ pọtìrì nìtẹlé
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ó [um] mà ṣe ó ilé yá pa àwọn ọmọ [um] iléèwé méje
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
wọn ti mú obìnrin yìí ọwọ ẹrú ló ń fàwọn ọmọ ọlọmọ ṣe
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
olórí àwọn asòfin ṣubú lulẹ làbójà wọn ti gbé e dìgbàdigba lọ síléèwòsàn
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ọpẹ o wọn ti ju ọgá olórin juju àtàwọn ọmọọṣẹ rẹ tí wọn jí gbé sílẹ
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ọpẹ o wọn yóò bẹrẹ sí í wá epo rọbì nípìnlẹ ogun láìpẹ abiodun
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
wọn ti mú àwọn géńdé méjì tí wọn ń jí wáyà iná ìjọba ká
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ó gbẹnu tán pásítọ ajíbòye tó fipá bá mẹta nínú ọmọ ìjọ rẹ lò pọ ńlọrọrìn ní iṣẹ èṣù ni
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
pọtidé [um] borí ọtá ẹ ò fẹsẹ dá bátànì sí [um] òṣèré tìata yìí lára
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ìmáàmù jáde ló kó wọlé mọ iwájú mọṣáláṣí làwọn agbébọn pa á sí
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
emmanuel ń lọ sẹwọn o ìbọn ìléwọ ni wọn bá lọwọ ẹ
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ó mà ṣe o àwọn agbébọn tún fẹmí èèyàn méjì ṣòfò ọpọ fara pa
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ẹyin ará ondo [um] ẹ máa múra sílẹ fún ìfẹhónú hàn tó lágbára [um]
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ìdájọ ọlọrun ti dé ọ ilẹ ọkàn nínú àwọn àáfàá àáfàá tó gé orí èèyàn jóná gbúgbúrú ńìbàdàn
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ó ṣẹlẹ iléẹjọ [um] tó ga jù lọ nílé wa da ẹjọ àtìkú [um] nù
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
àwọn ọmọ ẹgbẹ òkùnkùn black axẹgbẹ iṣẹ wọn dé germany mọkànlá ni wọn ti mú nínú wọn
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
dorcas fomi gbígbóná bo ọkọ ẹ lára bíi ṣákì ní meiran ó lọ ń gbé nǹkan gbẹyìn òun
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ìdìbò gómìnà ọjọ owó ń rọ fáwọn olùdìbò àti àwọn tó ń ra ìbò
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ó ó gbẹnu tán wọn ti mú kánṣẹlò tó ń digunjalè
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ẹgbẹ olókadá e gbà wá o àwọn apaniṣòwò tí fee [um] pa wá tán lẹkìtì [um]
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
pọtidé olórin ti jẹun sókè èyí lohun tó tún ṣe
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ó mà ṣe o ogunjìnmí ajàgàjìgì oògùn ti kú o
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ọmọ ẹgbẹ òkùnkùn [um] ní sodiq níbi tí wọn ti ń ṣèpàdé [um] lọwọ ni wọn ti mú un
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
mọǹṣàrútù ọdún karùnún rèé tọkọ mi [um] kò ti ṣojúṣe rẹ nínú ilé mo ẹ tú wa ká [um]
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ó mà ṣe o wọn sì pa ọgá àwọn òṣìṣẹ ìjọba ìpínlẹ ọyọ yìí sínú ilé ẹ nìbàdàn
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ìdájọ iléẹjọ tó ga jù lọ kì í [?] ṣe òpin ìrìnàjò mi nídìí òṣèlú
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
láti [um] benue làwọn ọrẹ méjì yìí ti jí ọmọ gbé ìpínlẹ èkó lọwọ ti tẹ [um] wọn
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ọwọ ìta di wàhálà láàrin olókàdá àtàwọn agbéró ẹnì kan kù
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
wọn [um] mú ògbólógbòó adigunjalè ńlọrọrìn nìyá ẹ bá dákú gbọnrangandan nígbà tí wọn ń [um] lù ú
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
èyí ni ohun tí àáfà òkùtagídí ṣe fún taniọlọhun
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ayé ti bàjẹ o ẹ wo ohun tọmọbìnrin yìí ṣe [?] nítorí owó tí kò sí lọwọ rẹ
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
peter obi ṣàbẹwò sáwọn tí [um] sójà ilé wa jù [um] bọmù fún ọ fún wọn lẹbùn owó
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
dúkìá kwara hotel làwọn eléyìí [um] lọọ jí kó tọwọ fi tẹ [um] wọn ńlọrọrìn
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
sífù dífẹǹsì mú ògbólógbòó adigunjalè méjì ńlọrọrìn
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
àjálù ńlá lágbo òṣèré òṣèré ọlọfínà ti jáde láyé
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
a fẹ kíjọba yí orúkọ fáṣítì ìlọrin padà sí fásitì shepherd alímì ẹgbẹ ọmọ ìlọrin
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
gomina ìpínlẹ edo kéde ẹgbẹrún lọnà àádọrin naira owóoṣù òṣìṣẹ tuntun
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
irú kí wàá lélẹyìí badmus gan mọnà níbi tó ti ń rí pátákó ìpolongo sáàrin ìlú
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
[um] damiláre já wọ ilé onílé ó kó wọn lẹrú lọ díẹ ló kù káwọn aràádúgbò lù [um] ú pa
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ali ndube mo fara mọ kí wọn máa pa olóṣèlú tó bá jí owó ìjọba ṣùgbọn
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ìjàḿbá oko gbẹmí èèyàn kan àwọn méjì mìín fara pa ńlọrọn
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ọmọ ọràn ọmọ ọràn alksom fọbẹ gún bàbá rẹ pa lọdún tuntun
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
nítorí adájọàgbà ìpínlẹ ọṣún àwọn òṣìṣẹ kóòtù fẹhónú hàn
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
èyí [um] nìdí tí mo fi [um] ń lu ìyàwó mi àtàwọn ọmọ tó bí fún mi nígbà gbogbo
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
iléẹjọ tó ga jù lọ da ẹjọ peter obi nù wọn ní tinubu ló wọlé ìbò ààrẹ
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
lẹyìn ọjọ méjì lákàtà àwọn ajínigbé olóyè àtàwọn ọmọdé mẹta [um] tí wọn jí gbé gbòmìnira ní [um] kwara
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
láti dín owó tíjọba ń ná kù èyí lohun tí tinubu ṣe
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
irú kí wàá lélẹyìí akẹkọọ iléèwé girama gún olùkọ rẹ pa lákòókò tó ń darí lọ sílé
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
àwọn agbébọn jí nọọsì gbé lọsun mílíọnù mẹwàá ni wọn ń béèrè
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
[um] nítorí tó sọ òótọ ọrọ [um] nípa ìjọba nípa ìjọba tìǹbù wọn gbaṣẹ lọwọ ọgá èso ojú pópó ní kwara
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
láàrin wákàtí díẹ tí wọn wọn kéde ikú akérèdọlù àwọn ọmọlẹyìn rẹ mẹta kọwé fipò sílẹ
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ó mà ṣe o èèyàn mẹẹẹdọgbọn jóná kú nínú kú nínú ìjàmbá ọkọ ńlọrọrìn
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ìbínú burúkú ti gbé adébáyò dé ọgbà ẹwọn kirikiri ọrẹ rẹ ló gùn pa
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
mi ò kábàámọ pé mo darapọ mọ ẹgbẹ òkùnkùn nítorí àǹfààní wa níbẹ ọpẹyẹmí
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
[um] irú ọmọ wo wàá léyìí ó [um] sì bínú pa ìyá àti àbúrò rẹ
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ìdájọ iléẹjọ tó ga jù lọ èyí lọrọ táwọn èèyàn sọ
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
òṣèré tìata táwọn ọlọpàá yìnbọn lu èyí nípò tó wà lọsibítù tí wọn gbé e lọ
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ẹrín àlùfáà ìjọ yarí lọjọ ìgbéyàwó kò so tọkọtìyàwó pọ èyí lohun tí wọn ṣe
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ọpẹ o àwọn ajínigbé ti [um] yọǹda pásítọ ìjọ rìdíìmù tí wọn jí gbé [um]
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
nítorí ọwọngógó oúnjẹ èyí làwọn òfin tí ọṣémáwé ṣe fáwọn ọlọjà l ondo
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ó mà ṣe o àwọn méjì dágbére fáyé lẹyìn tí wọn mú agbo jẹji tán nìpè àkọkọ
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
wàhálà ń bọ [um] ọ port ní kókó [um] zaria onímọtò gbàyàwó òun
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
rábìú yìí dájú o ò jí ọmọ ẹgbọn ẹ gbé ló bá pa á dànù
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
wọn ti mú saheed inú ìbọwọ ìbọwọ táwọn tó ń ja ẹṣẹ máa ń lò ló kó egbòogi olóró sí
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
[um] lẹyìn ikú akérèdọlú ayédáiwa di gómìnà [um] ìpínlẹ ondo ó kéde àwọn tí yóò bá a ṣiṣẹ pọ
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
èyí lohun tíjọba ṣe fún olórí àwo ìtàpá
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
egbòogi olóró ni danjúbà ń gbé lọ sórílẹèdè italy tọwọ fi tẹ é
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
owó ọlọpàá tẹ akẹkọọ akẹkọọ pọlì pẹlú fọọmù ìgbaniwọlẹ sínú ẹgbẹ òkùnkùn ńlọrọrìn
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ó dojú ẹ adájọ tún ran ọba àlàyé miín léwọ nípínlẹ ogun
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ó ṣẹlẹ port àti pasuma ti dá wàhálà sílẹ ní ṣọọṣì ṣẹlẹ o
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
wọn ti mú patrick fóònù rẹpẹtẹ lọ lọọ jí nínú ṣọọṣì rìdíìmù kan làkúrẹ
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ayé tí bàjẹ o ọkọọdún mẹwàá jí kọńgò àgbàdo márùnún gbé lọlọpàá bá tì í mọlẹ
|
YECT3F5
|
46-59
|
EV
|
female
|
End of preview. Expand
in Data Studio
No dataset card yet
- Downloads last month
- 3