text
stringlengths 30
107
| audio
audioduration (s) 3.7
16
| speaker_id
stringclasses 1
value | age_group
stringclasses 1
value | domain
stringclasses 1
value | gender
stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
ta ni ó bẹrẹ fuji ta ni àgbà nínú gbogbo olórin fuji kollington fèsì sí ìbéèrè ńlá
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
abiru kò lẹtọọ láti díje nínú àtúndí ìbò asòfin èkó
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
àwọn òṣìṣẹ ilé ẹjọ gíga ìpínlẹ ọṣun àtàwọn ọlọpàá gbẹná wojú ara wọn
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
covid ti di àjàkálẹ àrùn káàkiri àgbáyé káàkiri àgbáyé
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
kí ló ń fa ikú àìtọjọ láàrin àwọn ọdọ tó ń japá láti nàìjíríà ní uk
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
àwọn wo ni [um] ó jẹ àǹfààní ẹgbẹrún mẹẹdọgbọn tí ìjọba àpapọ [um] fẹẹ pín fáwọn aráàlú
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
owó ti tẹ méjì nínú àwọn tó dáná sun ṣọọbù mẹẹẹdógún lọjà àgbèní nígbàdàn
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
tẹgbọntàbúrò wà lára àwọn tiléẹjọ dá sẹwọn lórí ẹsùn bíba ààfin akire jẹ
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
kò sí ọgá iléèwé tó gbọdọ ta aṣọ fáwọn akẹkọọ lọsùn ẹgbẹmọdé
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
kàyééfì ńlá òkù ọrun wọlé ìbò lamẹríkà
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
super eagles e lọ lu benin republic mọlẹ ọmọ nàìjíríà wa lẹyìn yín mínísítà
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
málíkì tún lọọọ lọọọ jalè lẹyìn tó tẹwọn dé ní saki
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ìyàtọ díẹ ló wà nínú trump amerika àti buhari nàìjíríà
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
owó tẹ méjì nínú àwọn tó àwọn tó sún ọlọpàá jẹ lásìkò sars níìbàdàn
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ìdìbò gómìnà ọjọ owó dunlẹ fáwọn ọnì kátàkára ìbò
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
iléeṣẹ ọlọpàá ìpínlẹ ọyọ bẹrẹ àyẹwò ọpọlọ fáwọn sars
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ìrírí mi pẹlú àwọn ọlọpàá lójú pópó ló sọ mí di adisa o ní atm
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
bí wọn ṣe ya sinimá àyínlá ọmọwúrà rèé bbc yorùbá fọrọ wá àwọn òṣèré lẹnu wò
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
màmá gestola dolóògbé lẹyìn tó lùgbàdì covid
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ajayi tó ń fìbọn oníke jálẹ nínú kẹkẹ marduká tí kò ṣàkólò ọlọpàá lẹkọọ
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
gomina ìpínlẹ ọyọ bẹbẹ ẹyin ọlọpàá ẹ padà [um] sígboro ìjọba mi kò ní í wò yín [um] níran
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
wo àkójọpọ ìlérí táwọn olùdíje gómìnà lọyọ ṣe faraàlú níbi ìpàdé ìta gbangba bbc yorùbá
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
báwo ni àgbà òṣèré joe muizawa ṣe láyà tó
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
kà nípa nǹkan tí o nílò láti jàǹfàní ẹyáwó tí ìjọba fẹ pín fáwọn òǹtajà
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
alágídí nìyàwó mi kì í bọwọ fáwọn ẹbí mi mi ò fẹ ẹ mọ
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
àwọn èèyàn kwara tú jáde bíi èṣù nígbà tí wọn fojú kan sàràkí ńìlọrin
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
lótámà ọlọpàá ti padà sígboro ni wọn bá ní káwọn onímọtò sọra wọn lẹkọọ
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
màmá arsenal ṣeé débi ère ẹgbẹ kan ti fún màmá lẹbùn owó
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
real madrid gbàdé ògo la liga messi ní barcelona ò lè ta pútú mọ
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
fàyọṣe bẹ igbákejì gómìnà ondo ò ní kó padà sínú ẹgbẹ pdp
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
olivier giroud fi aramọnà góòlù méjì ṣayẹyẹ ìfẹsẹwọnsẹ ọgọrùn ún tó gbá fún france
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
àwọn aṣòfin ní káwọn alága ìjọba ìbílẹ mẹtàlá lọọ rọọkùn nílẹ lọyọọ
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ẹgbẹ òṣìṣẹ fún akérèdólú lọjọ mẹjọ péré kò fi sanwó oṣù tó jẹ wọn
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
tìrìlónú kan àti díẹ ni ìpínlẹ èkó yóò ná lọdún tó ń bọ fún iṣẹ ìlú
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
òṣìṣẹ ètò ìlera yóò jẹjọ lórí ikú maradona
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
bọlá are kẹnu bọ ọrọ lórí àwọn èdè orin àti ìhùwàsí àwọn olórin ẹmí lóde òní
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ọpẹ o olórí sílẹkùnọlá ogunwúsì bí ọmọkùnrin làǹtì lanti
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
kí ló kàn fún arsenal báyìí lẹyìn tí burnley yẹyẹ wọn mọlẹ ní dubai
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
nítorí ìjàḿbà ọkọ iléèwé poli ofa kéde ìsinmi ọjọ méjì fáwọn akẹkọọ
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
owó tẹ abẹdẹgídà àti ọrẹ ẹ tí wọn ń fi ọkadà jalè lákùrẹ
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ojútì ìrẹnijẹ àti ìyá àìkàwé nídìí iṣẹ tíátà tí ọpọ òṣèré padà sí fásitì
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ọba àwọn góòlù athemeyang àti saka sa newcastle pa lálẹ ọjọ ajé
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ẹrù ń ba àwọn agbábọọlù premier league [um] láti padà sórí pápá nítorí [um] covid
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
iléẹjọ tó [um] ń gbọ awuyewuye ìdìbò ni jẹgẹdẹ lẹtọọ láti [um] ṣàyẹwò àwọn ohun èèlò ìdìbò
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
kò sẹni tó lè yọ ọjọgbọn akítọyẹ nípò aṣáájú yorùbá
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
àwọn dókítà bẹrẹ ìyanṣẹlódì loǹdó wọn wọn lakérédólù kò sanwó osù fáwọn
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ẹ wo àwọn wòlíì nàìjíríà tí wọn ti sọ àsọtẹlẹ pé trump ni yóò wọlé lamẹríkà lẹẹkejì
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
alága ìdúró mú ohùn mi lọ lójú agbo tí mo ti ṣe alága ìjókòó lamẹríkà
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ìdá mọkàndínlọgọrùnún àwọn olùdámọràn ayélujára [um] kò [um] kò rí àyè wọn tó
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ọjà àgbálátà ní badáy rèé níbìtì ẹran ẹjọ ti dùn ju ẹran adìẹ lọ
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ìdí tí ẹgbẹ òsèlú apc yóò fi wọlé ní nàìjíríà àti àáríngungun ìpínlẹ ọyọ [?] rèé olùdíje ipò seneto
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ogun ni ọmọ wẹwẹ àti aláboyún ti ń kú jùlọ lọdún kó bọjú olùdíje gómìnà aa
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
leicester sèso ìyá fún man united man city gba ife ẹyẹ premier league ti sáà yìí
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
àwọn mẹta tí [um] wọn fẹsùn ìpànìyàn kan lọṣọgbọ ti [um] dèrò ẹwọn
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
iléẹjọ ní kí tòkè mákínwá san mílíọnù kan náírà fún ọkọ ẹ tẹlẹ
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
èyí làṣírí ohun tó kó bá donald trump tó fi pàdánù ipò rẹ
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
amẹríkà ṣetán àti ta bàlúù ọmọògùn fún nàìjíríà
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
nítorí ẹsùn ìkówójẹ àwọn aṣòfin ogun ránṣẹ pe ọgá opec tẹlẹ
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
[um] lóòótọ lóòótọ ni mo [um] wí fún yín ìjọba yìí ò dáa
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ayé mà níkà ó tottenham yá aṣọ iyì mọ manchester united lára nírọlẹ ọjọ ìsinmi
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
[um] mo gbé àpótí aṣọ mẹta [um] tí bàbá mi fún ọgá mi láti ṣeré tíáta ebi bá gbógun tì mí
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
kàyééfì àwọn agbébọn tú olórí ìjọba guinea tẹlẹrí sílẹ
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ìran ni mo lọ wò lójú agbo àríyá níwájú ilé bàbá mi tí mo fi pàdé tinubu
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ẹ fura o àwọn fúlàní bọrọrọ bíi bọrọrọ bíi ọọdúnrún ti ya wọ ìlú ibojàn
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
akẹkọọ iléẹkọ girama mẹfà rí ẹwọn he
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
mọtò pa olókàdá [?] nìbàdàn ni wọn bá fìbínú dáná sun ún
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ìyá ìbejì kò rántí nǹkankan [um] mọ ẹnu tí wọ sí ẹgbẹ kan ọmọ ìyá ìbejì ọmọ aráyé lé [um]
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
àwọn jẹsì tó gbajúmọ nínú ìtàn ìdíje bọọlù
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
nàìjíríà san bàǹtẹ ìyá fún benin ó tún kojú òsùnwọn fún fún nations cup
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
[um] mi ò ní í bá wọn bu tinubu bẹẹ ni [um] mi ò bá mákindé ja fáyọsé
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
àwọn ajínigbé jí aláàjì ismail lawal gbé nìbàdàn
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
òṣèré tìata láìdé bàkórè ṣe ìgbéyàwó ẹlẹẹkẹta
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
endsars kò tíì tán torí ìjọba kò tíì fi ọlọpàá arúfin kankan jófin
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
gíìwà fáṣítì àdẹkùnlé ajásìn sábẹwò sí ẹka rẹ nìbàdàn
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
[um] háà ó má ṣe ọ èèyàn méje kù lójijì
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
àṣàyàn inú ọrọ tí tinubu bá àwọn ọmọ nàìjíríà sọ lọdún tuntun nìyí
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
mọtò forí sọ igi nìbòdì lèèyàn kan bá kú lẹsẹkẹsẹ
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ọwọ ọlọpàá tẹ ayédèrú ahmed musa tó ń lu àwọn èèyàn ní jìbìtì ní jìbìtì
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
[um] mo rẹ pé ẹgbọn mi nínílá [um] ń jowú mi
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
dókítà tó ṣe iṣẹ abẹ fún oyún inú lamẹríkà ló ń sọ yorùbá yìí bíi ẹni lá oyin
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
akẹkọọ poli ọfà mẹrin fara pa nínú ìjàgbá ọkọ ní kwara
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
àwọn mọlẹbí ṣètò àdúrà fún ọwọláwà ọmọ òmùaran tó di aṣojú nílẹ amẹríkà
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
àwọn aṣòfin èkó fẹẹ ṣèrànwọ fáwọn tó pàdánù dúkìá wọn lásìkò ìwọde sars
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
donald trump dúpẹ lọwọ àwọn ọmọ nàìjíríà ó ní wọn wú òun lórí gidi
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ọmọ láńlòódù ọmọ láńlòódù gun ayálégbé bàbá rẹ pa
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
mo [um] ti fẹyàwó kejì mi ò [?] ṣe mọ ọkọ ìyàwó [um] kan
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
mo jẹ sẹgẹ ìyá lẹnu iṣẹ tíátà sẹyìn ṣùgbọn mi kò kábàmọ rárá
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
arsenal rántí invincibus ó pé ọdún mẹrìndínlógún tí arsenal gba ife premier league
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
chelsea fi ogun ẹyìn ja manchester city ṣaájú ìfẹsẹwọnsẹ àṣekágbá champions league
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ó nira láti gbàgbọ nígbà tí ọlọrun ní kí n kúrò ní america ló dá ìjọ sílẹ ní éṣíè kwara
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ọlọpàá ti bẹrẹ ìwádìí lórí túnjí táwọn kan pa sínú ilé ẹ nìbòkun
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
àwọn ọlọpàá fẹhónúhàn pé wọn ò rówó àjẹpọnú gbà
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ọlọrun ló rán mi níṣẹ láti díje dupò gómìá ìpínlẹ ogun lábẹ ẹgbẹ anepp
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ohun mẹwàá pàtàkì nípa maradona àti ìbásepọ rẹ pẹlú ẹlẹsẹ ayò ẹlẹsẹ ayò diego costa rèé
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
iléeṣẹ ọlọpàá ti mú àwọn ọmọ kéékèké tó ń ṣe ẹgbẹ òkùnkùn lẹkọọ
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
má bínú sí [um] mi basketballmouth rawọ ẹbẹ sí ay [um] àti àwọn [?] miran
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
lẹyìn wákàtí díẹ [um] táwọn dókítà bẹrẹ ìyanṣẹlódì àwọn agbẹjọrò ìjọba náà bẹrẹ tiwọn [um] londo
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
nítorí ọrọ ilé àwọn ajàgbàgbàlẹ lu kábíyèsí dé ọsibítù lọfàfẹmí
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ẹgbẹrún lọnà ọgọrùnún náírà ni mo ta orí àti owó akẹkọọ fásitì ife
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
|
ọpọ ẹgbẹ agbábọọlù mójú lọ sọjà bí kàkàkà agbábọọlù ṣe dópin
|
YECT3F8
|
46-59
|
EV
|
female
|
End of preview. Expand
in Data Studio
No dataset card yet
- Downloads last month
- 4